Democratic Green Party of Rwanda

Democratic Green Party of Rwanda
French nameParti vert démocratique du Rwanda
Kinyarwanda nameIshyaka Riharanira Demokarasi no Kurengera Ibidukikije
ÀrẹFrank Habineza
Ìdásílẹ̀14 Oṣù Kẹjọ 2009 (2009-08-14)
Ọmọ-ẹgbẹ́500,000 (claimed)[1]
Ọ̀rọ̀àbáGreen politics
Green liberalism
Liberal democracy
Ipò olóṣèlúCentre to centre-left
Ìbáṣepọ̀ akáríayéGlobal Greens
Chamber of DeputiesÀdàkọ:Composition bar
Ibiìtakùn
rwandagreendemocrats.org

Ẹgbẹ́ òsèlú Democratic Green Party of Rwanda (DGPR; Faransé: Parti vert démocratique du Rwanda, PVDR; Àdàkọ:Lang-rw, IRDKI) jẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú kan ní Rwanda, tí wọ́n dá kalẹ̀ ní ọdún 2009. Wọ́n ṣe ìforúkọsílẹ̀ ẹgbẹ́ náà ní oṣù kẹjọ ọdún 2013, nítorí pé ó pé kí wọ́n tó fi orúkọ ẹgbẹ́ náà sílẹ̀ ní ọdún 2013, wọn kò padà ní àǹfààní láti kópa nínú ìdìbò sílé ìgbìmọ̀ aṣofin Rwanda ti ọdún 2013. Ète ẹgbẹ́ òsèlú náà ni láti lo àwọn ọ̀nà tí kò mú wàhálà dání, jà fún dídín owó àwọn ǹkan ọ̀gbìn àti oúnjẹ kù. Wọ́n gbàgbọ́ pé ara ẹ̀tọ́ àwọn ènìyàn ni "ẹ̀tọ́ sí ẹ̀mí, òmìnira, ìpàdé àlàáfíà, láti sọ tinú wọn jáde, láti sìn Ọlọ́run wọn àti láti ṣe ǹkan tí ó ń fún wọn ní ìdùnnú", àti pé Ọlọ́run ni ó ń fún yàn ní àwọn ànfàní yìí.[2]

  1. "Rwanda's only registered opposition party picks candidate to face Kagame". Africa News. 
  2. "National Political Platform". Democratic Green Party of Rwanda. Archived from the original on 23 June 2018. Retrieved 23 June 2018. 

© MMXXIII Rich X Search. We shall prevail. All rights reserved. Rich X Search